Itumo Iriran Ala Ati Saara

Call Directions Contact the establishment

Itumo Iriran Ala Ati Saara 100% Problem solver, Astral Psyche Consultant, A Mystic, Healer, Soul Therapist, Life Planner, Certified Herbal Practitioner, Spiritual Healing
(1)

A NKI WA KU OJUMỌ ÌṢẸGUN ỌJỌ ONÍ YÌÍ KI O LEKUN NÍ ÀGBÀRÁ ÌṢẸGUN KI O LÉKÈ GBOGBO AWỌN ALABURU ẸDÁ
22/09/2026

A NKI WA KU OJUMỌ ÌṢẸGUN ỌJỌ ONÍ YÌÍ

KI O LEKUN NÍ ÀGBÀRÁ ÌṢẸGUN
KI O LÉKÈ GBOGBO AWỌN ALABURU ẸDÁ

OGÓ TI O NṢIṢẸ TI KÒ NI ÌSINMI KÌÍ DALẸ. BI ÀRÀ TÍ ṢE MAA NFẸ ISINMI, BẸẸ NÁÀ NI ÒGO. Ọpọlọpọ Ògo ló tí dì Ọlẹ tàbí tí ò...
21/09/2026

OGÓ TI O NṢIṢẸ TI KÒ NI ÌSINMI KÌÍ DALẸ. BI ÀRÀ TÍ ṢE MAA NFẸ ISINMI, BẸẸ NÁÀ NI ÒGO.

Ọpọlọpọ Ògo ló tí dì Ọlẹ tàbí tí òmíràn títàn. Ki ọta tóo leè rí ní mú, Ògo Eni ní wọn máa ngbiyanju láti tẹ lórí bá. Bi Ògo bá tí lẹ, O rọrun kí Ọwọ Awọn Ẹni Aburú mú ni Irọrun.
Ti Ogo Ẹdá ba nṣiṣẹ lai Ni Isinmi, o leè fa ki o tètè já, Eyi tí o l'agbara jù ní Ẹni tí O ha wọ ti kìí ṣe Itọrẹ.

KỌKỌRỌ ÀGBÀRÁ TI O LEÈ ṢILẸKUN GBOGBO BẸẸ NÁÀ NI TÍ O LEE TI NÍ ỌRỌ ÀṢẸ JẸ.   IGBEERO RẸ NÍ ÀGBÀRÁ TI O TÓBI NÍNÚ IṢẸMI ...
21/09/2026

KỌKỌRỌ ÀGBÀRÁ TI O LEÈ ṢILẸKUN GBOGBO BẸẸ NÁÀ NI TÍ O LEE TI NÍ ỌRỌ ÀṢẸ JẸ.

IGBEERO RẸ NÍ ÀGBÀRÁ TI O TÓBI NÍNÚ IṢẸMI RẸ.
TI ÌGBÀGBỌ ISỌRỌ SÍNÚ AIYÉ RẸ BA NJẸ TI DÁRADÁRA ÀTI A RI DAJU NÍ GBOGBO ÌGBÀ, YÍÒ MÁA YÍ AIYÉ RẸ PADÀ SI ỌTÚN BI O TI ṢE RÒ LỌKÀN.

TI ỌPỌLỌPỌ IRORI ATÍ IGBEERO RẸ BA NJẸ TI ABURÚ SÍNÚ IṢẸMI RẸ, O LEÈ MÚ ÌPARUN KÍÁKÍÁ BA IRÚ IṢẸDA BẸ...........

RO EERO RÉRÉ KI O SÍ SỌ DÁRADÁRA SÍNÚ EMI ÒGO RẸ

IGBA ÀTI ÀSÌKÒ NII ṢE PẸLU ÒGO..............     MO ṢE NI ÌWÚRE FÚN Ọ L'ỌJỌ ÒNÍ YÌÍ ÀKÓKÒ WÀHÁLÀ RẸ KO NÍÍ JA SÓFO
21/09/2026

IGBA ÀTI ÀSÌKÒ NII ṢE PẸLU ÒGO..............

MO ṢE NI ÌWÚRE FÚN Ọ L'ỌJỌ ÒNÍ YÌÍ
ÀKÓKÒ WÀHÁLÀ RẸ KO NÍÍ JA SÓFO

KI OHUN IKÚ MA ṢE SỌLẸ SÍ ILÉ RẸ. OHÙN AIDARA MA ṢE ṢẸLẸ SI ỌDẸDẸ RẸ
14/09/2026

KI OHUN IKÚ MA ṢE SỌLẸ SÍ ILÉ RẸ. OHÙN AIDARA MA ṢE ṢẸLẸ SI ỌDẸDẸ RẸ

ASHINA ÌDÀGBÀSÓKÈ ÀTI OWÓÌlànà yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àṣírí láti sí àwọn ilẹ̀kùn owó fún ọ, kí ohunkóhun má baà dènà mọ...
05/09/2026

ASHINA ÌDÀGBÀSÓKÈ ÀTI OWÓ

Ìlànà yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àṣírí láti sí àwọn ilẹ̀kùn owó fún ọ, kí ohunkóhun má baà dènà mọ́ ọ̀nà rẹ.

ÀWỌN NǸKAN TÍ O NÍ LO:
👉🏽 Èwe Orijin — 7 fún obìnrin, 9 fún ọkùnrin).
👉🏽 Ata wẹ́wẹ́ (ata ìjọsi) 7 tàbí 9.
👉🏽 Ẹyin adìẹ ìbílẹ̀ kan.
👉🏽 Epó pupa.

ÌLÀNÀ RẸ̀:
Lọ èwe náà pẹ̀lú ata wẹ́wẹ́ pọ̀, fi iyọ̀ díẹ̀ sí i, kí o sì ro papọ nínu abọ́ kan. Fo ẹyin adìẹ ìbílẹ̀ yẹn sí i, kí o sì pò papọ̀ dáadáa bí ẹni to nfẹ dín ẹyin (omelette).
Fọ ìkòkò tàbí apẹ rẹ mọ́ tónitóni. Da epó pupa díẹ̀ sínu ìkòkò náà, jẹ́ kí ó gboná, lẹ́yìn náà da ẹyin tí o tì pọ̀ yẹn sí i láti dín in. Tò ó sínu àwo títún kan.

ASIKO RẸ:
Ní òru, ṣáájú kí o tó sùn, bẹ Ọlọhun lórí Gbogbo Ẹda rẹ nínú atẹ́gùn, ilẹ̀, àti gbogbo ohun tó wà nínú ẹ̀dá láti ṣí ọ̀nà fún ọ, kí wọ́n sì mú owó wá fún ọ láti gbogbo kọ̀rọ̀ ayé.

ÈTÒ RẸ:
Jẹ ẹyin dín-dín náà, kí o sì lọ sùn tààrà.

APẸRẸ
Tí ọ̀nà bá jẹ dáadáa fún ọ
wàá lá àlá rere ní òru ọjọ́ náà. Ṣùgbọ́n tí o bá lá àlá pé ò ń bá ẹnìkan ni ibalòpọ̀ tàbí pé o rí obìnrin/ọkùnrin ní apá rẹ, ó túmọ̀ sí pé àwọn Alágbára míràn nṣe Àtakò láti má ṣe jẹ kí O gbà fún ọ láti ṣe ohun tí o béèrè (dúró fún ìgbà díẹ̀ kí o tó tún dán wò).
Dán an wò kí o sì rí iṣẹ́ ìyanu ti Ọba Adẹ̀dá.

FÚN ẸNI TÍ ÌDÈNÀ TÀBÍ ÌJÀMBÁ ỌTA PỌ FÚN.  Ki A Ra Obì Gbanja (Òbí Fúnfún) kì O pọ niwọn ba. Kí A lọ kunna. Kí A fi Orí A...
04/09/2026

FÚN ẸNI TÍ ÌDÈNÀ TÀBÍ ÌJÀMBÁ ỌTA PỌ FÚN.

Ki A Ra Obì Gbanja (Òbí Fúnfún) kì O pọ niwọn ba. Kí A lọ kunna. Kí A fi Orí Amo po papọ dáadáa. Kí Òbí náà pọ dáadáa jù Orí yìí lọ. Kí A bù Omi Ọmu Maalu oojọ sí. Kí A sá sí Ààyè ibojì (Tí Oòrùn ko ti nii pa A). Aó máa bù sí Omí iwẹ diẹdiẹ

Ọnà Òòrè máa lá bẹẹ náà ní Iyatọ máa dé sínú Aiye Ẹni náà. Ọwọ Burúkú máa kúrò lára rẹ

𝐏𝐋𝐀𝐍𝐄𝐓𝐀𝐑𝐘 𝐑𝐔𝐋𝐈𝐍𝐆𝐬 𝐅𝐎𝐑 𝐖𝐄𝐃𝐍𝐄𝐒𝐃𝐀𝐘 (𝐒𝐞𝐩𝐭𝐞𝐦𝐛𝐞𝐫 𝟐𝐧𝐝, 𝟐𝟎𝟐𝟔)ASTROLOGICAL ALIGNMENT: Venus in Scorpio / Ta**usELEMENT: EarthCORE...
02/09/2026

𝐏𝐋𝐀𝐍𝐄𝐓𝐀𝐑𝐘 𝐑𝐔𝐋𝐈𝐍𝐆𝐬 𝐅𝐎𝐑 𝐖𝐄𝐃𝐍𝐄𝐒𝐃𝐀𝐘
(𝐒𝐞𝐩𝐭𝐞𝐦𝐛𝐞𝐫 𝟐𝐧𝐝, 𝟐𝟎𝟐𝟔)

ASTROLOGICAL ALIGNMENT: Venus in Scorpio / Ta**us

ELEMENT: Earth

CORE MEANING:
RELEASE WHAT's NO MORE IN USE
Qabla Daakhil (Amissio) signifies things slipping away, financial or emotional leakage, and the necessity of voluntary sacrifice. It indicates that trying to hold onto outdated situations today will cause distress.

THE PRESENT: Energy is flowing outward. You are spending more energy, money, or emotion than you are receiving.

THE CAUSE: A recent desire to force outcomes or hoard control has triggered a natural spiritual contraction.

THE OUTCOME: True gains today will only come through spiritual surrender and releasing what no longer serves your destiny.

MONEY & CAREER: Avoid major investments or binding contracts today.
Money spent today should be strictly for necessities or spiritual offerings.

RELATIONSHIPS: Misunderstandings can lead to a sudden emotional distance. Do not argue out of pride. Let go of the need to have the last word.

HEALTH: Guard your energy. You may feel physically drained. Hydrate and stay grounded.

*STRICT TABOOS TODAY* (Things to Avoid)

* ❌ No complaining about money:
Speaking poverty into existence today locks the energy of Amissio into your financial house.

* ❌ No wearing dark, heavy colors:
Avoid pitch black or dark grey.
Wear white or light yellow to repel heavy vibrations.

* ❌ No nocturnal traveling:
Try to be indoors before sunset to avoid hovering atmospheric astral energies (Ajogun).

OFFERINGS/SACRIFICE:

Items needed:
3 Cowrie shells/Money or 3 coins, Palm oil (Epo Pupa), Roasted corn/popcorn, and a small glass of Water.

ACTION: Step outside your front door. Pour a few drops of palm oil and Water onto the ground/porch. Place the corn and Money/coins next to it.

PRAYER: “O You My Creator, By through I channel the Spirits that's the deliverer of turning points, accept this today. Turn loss into profit. Block the feet of misfortune from entering my home.”

THE SPIRITUAL CLEANSING BATH (Ipara/Iwẹ)
To clear the aura of heavy Scorpio/Amissio Earth energies:
Crush fresh Scent leaves ( Nchanwu/Efinrin) or Mint leaves into a bucket of clean water. Add a single tablespoon of sea salt. Wash your face, hands, and feet while praying for total restoration.

𝐓𝐇𝐄 𝐀𝐋𝐈𝐆𝐍 𝐒𝐔𝐏𝐏𝐋𝐈𝐂𝐀𝐓𝐈𝐎𝐍 𝐈𝐒𝐋𝐀𝐌𝐈𝐂 𝐏𝐑𝐀𝐘𝐄𝐑.📖

Arabic:
اللَّهُمَّ إِنِّي أَعُوذُ بِكَ مِنَ الْهَمِّ وَالْحَزَنِ، وَالْعَجْزِ وَالْكَسَلِ، وَالْبُخْلِ وَالْجُبْنِ، وَضَلَعِ الدَّيْنِ وَغَلَبَةِ الرِّجَالِ

Transliteration:
“Allahumma inni a'udhu bika minal-hammi wal-hazani, wal-'ajzi wal-kasali, wal-bukhli wal-jubni, wa dala'id-dayni wa ghalabatir-rijal.”

The English Meaning
"O Allah, I seek refuge in You from anxiety and sorrow, weakness and laziness, miserliness and cowardice, the burden of debts and from being overpowered by men."

𝐓𝐇𝐄 𝐂𝐇𝐑𝐈𝐒𝐓𝐈𝐀𝐍 𝐏𝐑𝐀𝐘𝐄𝐑
Stand on the authority to command restoration, invoking 𝐉𝐨𝐞𝐥 𝟐:𝟐𝟓 (restoring the years the locusts have eaten).

THE WARFARE

"Heavenly Father, I thank You for Your mercy that is new every morning. On this Wednesday, I stand against every spirit of Losses—every power of loss, leaking blessings, and wasted efforts in my life.

RESTORATION PRAYER:
Lord, Your word says that You will restore the years and the resources that the devourer has stolen. I decree today that my finances will not leak, my health will not fail, and my peace will not be stolen.
Where the enemy has planned a subtraction, Father, bring Holy Ghost multiplication. I close every spiritual door to setbacks and open the windows of heaven over my career, my family, and my mind today. Guide my steps at every crossroad. In Jesus' mighty name, Amen."

ÀṢÍRÍ BIBO OWO NLAMo fi iṣẹ́ ÀṢẸ TÍ KÒ NÍ ÌYÍPADÀ YÌÍ TỌRẸ fún ọ. Èyí kì í ṣe Oògùn, Àṣírí àṣẹ tó ń jẹ́ bójúmọ́ tún mọ́ ...
31/08/2026

ÀṢÍRÍ BIBO OWO NLA

Mo fi iṣẹ́ ÀṢẸ TÍ KÒ NÍ ÌYÍPADÀ YÌÍ TỌRẸ fún ọ. Èyí kì í ṣe Oògùn, Àṣírí àṣẹ tó ń jẹ́ bójúmọ́ tún mọ́ ni—àṣẹ "Kí ó rí bẹ́ẹ̀, ó sì rí bẹ́ẹ̀."
Tí o kò bá nírúfẹ́ àràádọ́ta ọ̀pọ́lọpọ́ owó rí lórúkọ rẹ, tàbí tí ọwọ́ rẹ kò kò tẹ àràádọ́ta ọ̀pọ́ lórúkọ rẹ rí, iṣẹ́ yìí wà fún ọ láti fòpin sí ìpọ́njú náà.

ÌSÈTÒ RẸ 📝
O gbọ́dọ̀ kọ àwọn àmì ràmlì tàbí tìtẹ̀ yìí (Garian nínú ilé Masa Sulaimana, àti Sulaimana nínú ilé Adama) ní ọ̀nà (70 times) sí ara pákó ìkọ̀wé rẹ, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà nínú àwòrán naa. Lẹ́yìn náà, fọ̀ ọ́ jáde pẹ̀lú omi mímọ́ láti rí Hantu (Omi Ìyípadà Sínú Rere).
Lẹ́yìn tí o bá ti rí omi yìí, pín Hantu náà sí ọ̀nà méjì tó dọ́gba.

*ÌPÍN KÌÍNÍ*:
Ìwẹ̀nù Aláṣẹ Ọlọ́jọ́ Méje 🪵 🔥

1. Wá epo tàbí ewé bùndùlù méje (7 Bundles) Ògànwó Fúnfún ti Eleyinbo npe Ni (White Lannea Acida).
2. Kó àwọn Ewe yìí sínú ìkòkò ńlá kan, da ìpín kìíní Hántu náà sí i, kí o sì gbé e sínú iná. Sè é dáadáa títí á fi hó, á sì bọ̀ dáadáa.
3. Da omi gbígbóná náà sínú garawa mímọ́ kan. Lo omi yìí pẹlu kí Ese Rẹ máṣe kán ilẹ, kí o sì wẹ̀ náà pẹ̀lú rẹ̀, kí o sì mu díẹ̀ nínú rẹ̀ kí o tó sùn.
4. Ṣe ètò ìwẹ̀nù yìí fún òru méje lẹ́seẹsẹ (7 nights).

*ÌPÍN KEJÌ:*
Ìlànà Àṣẹ Ọlọ́jọ́ Mejìdínlógún (18-Day Controlling Souls) 🐜 🐜

1. Lọ sí orí ìbùdó tàbí kòtò àwọn kòkòrò amú nǹkan jẹ (Ant or Beetle hill)—níbi tí o ti rí àwọn kòkòrò tí wọ́n ń ru oúnjẹ sínú ihò wọn.
2. Fi ọwọ́ mímọ́ gba oúnjẹ ẹnu kòkòrò náà ní ọ̀nà Mejìdínlógún (18 pieces) lẹ́sẹsẹ lẹ́nu wọn.
3. Da oúnjẹ kòkòrò mọ́kàndínlógún (18 items) yìí sínú ìpín kejì Hántu naa.
4. Lẹ́yìn náà, wá lọ́fíńdà (perfume) tí O ń jẹ́ DOUNIA, da gbogbo rẹ̀ sínú rẹ̀.
5. Wá lọ́fíńdà kejì tí ń jẹ́ DANGOMA, da gbogbo rẹ̀ náà sínú rẹ̀ láti jẹ́ kí àṣẹ náà tì sínú rẹ̀ pátápátá.

LÌLÒ RẸ̀ LÓJOOJÚMỌ́ 🌅 🌃

* Ní Gbogbo Alẹ́: Fi omi Hantu ti o ti ní lọ́fíńdà yìí wẹ gbogbo ara rẹ pátápátá kí o tó sùn sí orí ibùsùn rẹ.
* Ní Gbogbo Àárọ̀: Ní gbà tí o bá jí, da díẹ̀ sínú ọwọ́ rẹ, kí o sì fi pa gbogbo ara rẹ pátápátá títí yóò fi pé ọjọ́ Mejìdínlógún (18 days).

Pẹ̀lú àṣẹ Ọlọ́run Ọba, lẹ́yìn tí o bá ti parí ètò yìí, kò le yí kọjá ọjọ́ kejìdínlógún (18 days) tí o kò ní rí iṣẹ́ ńlá, tàbí àwọn àǹfààní àràádọ́ta ọ̀pọ́lọpọ́ owó (millions of opportunities) tí yóò mú èrè gidi gidi wá fún ọ láti yí ayé rẹ padà sínú rere.

ÀṢẸ FÚN ÈTÒ IṢẸ YÌÍ WA FÚN AWỌN MEMBERS GROUP YII NÌKAN, KO LEE ṢIṢẸ FUN ẸLÒMÍRÀN.

OJUMO ÒÒRÈ ỌPẸ OJUMỌ ÒÒRÈ AYỌ OJUMỌ ÒÒRÈ ÌDÙNNÚ SÍNÚ AIYE ẸNI KỌỌKAN WÀ
26/08/2026

OJUMO ÒÒRÈ ỌPẸ
OJUMỌ ÒÒRÈ AYỌ
OJUMỌ ÒÒRÈ ÌDÙNNÚ

SÍNÚ AIYE ẸNI KỌỌKAN WÀ

Address

Lusada
Lagos
112102

Telephone

+2348036168165

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Itumo Iriran Ala Ati Saara posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Establishment

Send a message to Itumo Iriran Ala Ati Saara:

Shortcuts

Share