Omoge Asa

Omoge Asa I'm Ajibade Khadijat Folashade commonly known as Ife Akewi / Omoge Asa, a Nigerian Yoruba chanter, the CEO of Omoge Asa Cultura and Entertainment....

Omoge Asa n kiwa peAku Osu tuntun oNinu Osu tuntun YiIreti wa koni jasi asan🙏Oluwa yo ran oIuranlowo nla si wa🙏Oju kosi ...
01/09/2023

Omoge Asa n kiwa pe
Aku Osu tuntun o
Ninu Osu tuntun Yi
Ireti wa koni jasi asan🙏
Oluwa yo ran oIuranlowo nla si wa🙏
Oju kosi ni ti wa🙏
Osu tuntun yi a gbe Gbogbo wa o
Amin🙏

24/08/2023

Ijinle oro
Lati enu
Omoge Asa

Iya mi owon to dun.🤱Dear sweet mother.🤱Oluko mi, ore mi, ife mi akoko ati olutunu mi.👩‍🏫My teacher, my friend, my first ...
06/09/2022

Iya mi owon to dun.🤱
Dear sweet mother.🤱

Oluko mi, ore mi, ife mi akoko ati olutunu mi.👩‍🏫
My teacher, my friend, my first love and my comforter.👩‍🏫

Olutona mi, oluke mi, oloro mi, oluyesi mi.💏
My pathfinder, my caregiver, my confidant, my cheerleader.💏

Awokose mi, abanisoro iwuri mi, amona mi ti o ni suuru.🤶
My mentor, my inspirational speaker, my gentle teacher.🤶

E wa nibe nigba ti mo gbe ese akoko mi.🚶‍♀️
You were there when I took my first step and went unsteadily across the floor.🚶‍♀️

E wa nibe nigba ti mo rin erin akoko mi. 😁
You were there when I had my first laugh.😁

Eseun fun bi e se mo mi si obinrin daradara🙏
Thank you for molding me into a fine woman. 🙏

Eseun fun kiko ti e ko mi ni ififunni ati Ife.🙏
Thanks for teaching me how to love and give. 🙏

Eseun ti eduro ti mi nigba isoro🙏
Thanks for stand by in time of difficulty🙏

Nitooto iyebiye ti o sowon ni yin💎
You are a indeed a rare gem💎

Mo nife yin gidi gidi maami😍
I love you so much mother😍

Orí, pèlé, Atèté níran Atété gbe ni kòòsá. Kò sóòsà tíí dá ‘níí gbé lèyìn orí eni. Ori leja fii labu, ori lakere fii mej...
19/07/2022

Orí, pèlé, Atèté níran Atété gbe ni kòòsá. Kò sóòsà tíí dá ‘níí gbé lèyìn orí eni. Ori leja fii labu, ori lakere fii meja lale odo.
Bi o ba maa lowo, Beere lowo orii re.
Bi o ba maa sowo, Beere Lowo ori re wo. Eri nii gbeni taa fi n dade owo, ori nii gbeni ti afi tepa ileke.
Ori mi gbemi je ki n lowo lowo
Ori mi gbemi ki n ri taje se
Ibi ti ori mi oti sunwon ju ibi ti mo wa yi lo, ese mi ma salai gbemi debe🙏🙏

Ede Yoruba rewa ni siso Imura Yoruba rewa lasaIsesi Yoruba rewa nise Gbogbo Eya Yoruba lo wumi...Gbogbo Omo kaaro ojiire...
18/07/2022

Ede Yoruba rewa ni siso
Imura Yoruba rewa lasa
Isesi Yoruba rewa nise
Gbogbo Eya Yoruba lo wumi...
Gbogbo Omo kaaro ojiire edide, eje ka tunbo dijo gbe Asa wa laruge

Address

Alakia, Area Ibadan
Ibadan

Telephone

+2348087599353

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Omoge Asa posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Establishment

Send a message to Omoge Asa:

Share