21/02/2024
Keereee oooooooo .
Omo Odu to da iwa ,Oro Agba Ni oooooooo .
Oni ki omo oko ronu ,Oro yoruba gbero .
Baba Ogunnde ni ki yoruba ronu lojo ojosi Yoruba o funra ,bee ifunra loogun agba .
Hunnnnnn ,Ase Oro Ni awa lokan .
Yoruba o ronu moo ,won mo fe pelu obo jeko Lori oro Are tio ti lo osu mejo .
E funra oooooooo .
E ti gbagbe awon ipo ti omo oduduwa o ti de lati igba ti orile ede yi to wa ti omo tiyin are ti fi omo yin si .
Olorun nja fun yin e ti nbinu .
Oke oya nko onje pamo ki ijoba omo yin le daru .awon eya tihin na nlo agbara won Lori epo atigbogbo eya oko ki o le di owon gogo eee si funra ..
Teni ni teni e duro ti omo yin pelu Adura ki ose aseyori .
E yee paruwo ebi ,ka jeki is owo wa to was je .
OMO WA NI JE OSEEE .