Oduduwa TVRadio

Oduduwa TVRadio Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Oduduwa TVRadio, 33 kindersley Way, Abbots Langley, Watford.
(2)

OduduwaTVRadio radio is 100% dedicated to empowering Yoruba people to know their rights as citizens in their own language, through provision of key sections of our constitution in Yoruba language on our website www.OduduwaTVRadio.org

04/09/2026

Big shout out to my new rising fans!

Ayo Mide

03/09/2026

Ekale gbogbo ile, iru palapala wo ni awon Oselu wa tun nse yi, Kilode ti Oselu gbe journalist si Orunkun o wa nso pe ko lo nto ni, fi gba nti o fe, ba wo le se ri si?

03/09/2026

Oloye Sunday Igboho(Igboho Oosa) so pe, No time to waste time, te ba ti ri Fulani Ajinigbe pelu ibon, e pa danu!
👍🏿👍🏿

Wale Adedayo so pe won ti arrest oun o, “Dem don 'arrest' me for RockCity FM 101.9 in Abeokuta. Should be over soon sha!...
03/09/2026

Wale Adedayo so pe won ti arrest oun o, “Dem don 'arrest' me for RockCity FM 101.9 in Abeokuta. Should be over soon sha!”
A je ki e mo bo se nlo o, hmmm



03/09/2026

Ekaaro
Gbogbo ile, E sora fun nti ero pe o je original, se ti ri pe fake ni nti won nda si inu pali yen. Ba wo le se ri si

02/09/2026

Ekaasan, Ekale, Imam US mo ofin ilu Lori Esin Abala Kewa ni inu iwe ofin Nigeria so bayi ninu itumo lati ede Geesi si Yoruba” Ijoba ti Federation, tabi ipinle ko ni gba esin eyikeyi gẹgẹbi Ẹsin ipinle, A ro ki o fo awa oni isẹsẹ sile, ba wo le se ri si

“Lónìí ni ọjọ́-ìbí Baba Babatunde Bamgbode, Odun kẹtàdínlọ́gọ́rin (79),ẹ bá mi ṣe ayẹyẹ òṣèré Nollywood àgbà yìí, Ẹ kú o...
02/09/2026

“Lónìí ni ọjọ́-ìbí Baba Babatunde Bamgbode, Odun kẹtàdínlọ́gọ́rin (79),ẹ bá mi ṣe ayẹyẹ òṣèré Nollywood àgbà yìí, Ẹ kú oríire, Baba.” 🎂🎂🎉🎉🍾🍾🎁🎁

E darapo mo wa Lori OduduwaTVRadio2 Lori YouTube wa ki e ba wa subscribe, e gbo oro pataki lati owo Oloye Sunday Igboho ...
02/09/2026

E darapo mo wa Lori OduduwaTVRadio2 Lori YouTube wa ki e ba wa subscribe, e gbo oro pataki lati owo Oloye Sunday Igboho bi won se da IRU EKUN sile bi ipinle Ondo.

https://www.youtube.com/live/6cMq4n_nJOY?is=aJMpw46Qlq1rWn3C

Eseun

CHIEF SUNDAY IGBOHO DAEGBE IRU EKUN SILE NI AKURE ONDO ...

02/09/2026

Awọn ọdọmọkunrin oniwa buruku, ni a sọ pe wọn n kọlu awọn awakọ ni gbangba ọsan, ti wọn si n beere fun owo to to ₦500,000, won fe fo glass moto, ba wo le se ri si

02/09/2026

Ekaasan gbogbo ile, e jo a ro eyin elesin ajeji(Islamu ati Kristiani), e ye yo awon onisese lenu, won ni eto ni inu w
Iwe ofin ilu lati se isese, Abala Kewa ni inu iwe ofin Nigeria so pe, “Ijoba ti Federation tabi ti ipinle ko ni gba esin eyikeyi gẹgẹbi Ẹsin ipinle”
Ba wo le se ri si e ba wa da si

Address

33 Kindersley Way, Abbots Langley
Watford
WD5 0DG

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Oduduwa TVRadio posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share