Obirin rere ninu ile oko

Obirin rere ninu ile oko TO MAKE ALL WOMAN KNOW THERE RIGHT

17/10/2025

Won o ni lu Agogo iku ojiji ninu ile mi ati gbogbo owo to ba ri amin se aku ojumo 🫵🫵🫵🫵🫵

Ekaro gbogbo Ile ejeka soro fun ipara Lilo to ba ara je  🖐️🖐️🖐️🖐️🖐️
16/10/2025

Ekaro gbogbo Ile ejeka soro fun ipara Lilo to ba ara je 🖐️🖐️🖐️🖐️🖐️

16/10/2025
Fact about this life
16/10/2025

Fact about this life

14/08/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Akinsanya Olayinka, Funke Odusanya Daramola-Lawson, Akinwola Oboli Robert, Cecilia Tolulope, Dupe Durodola, Adenike Elizabeth Alowosile, Horlargunju Morenikeji Hardeyhorlar, Omolana Adeniyi, Emmanuel Abiola Adeoye, Sanni Morehenikeji Dharmilolah, Prince Adebayo Elijah Aboderin, Ezekiel TA Testimony, Oluwafemi Oluwasoji, Oluwafemi Babatunde, Opeyemi Salako Adeniran, Olawunmi Dorcas, Victoria Akinpelumi, Adedera Olaniyi, Adeyemi Bello, Adeniran Olalekan, Shola Ilesanmi, Simeon Timin, Anikee Abiodun, Karimu Amidu Alade, Aishat Zakariyah, Babalola Abinbola Hezekiah Kayode, Abraham Oyelade, Adewunmi Hikimat, Olanrewaju Ayinla, Hafeez Adeoye Adewale, Ayo Ola Mhi, Alhaja Ayo, Olarewaju Naheemdeen Abiodun, Taiwo Joke, Obondey Kehinde, Akingbeye Joshua, Olori Adeniyi, Kenny Shaw, Rukoyay Ganiyu, GahGah Gah, Olusegun Josephine, Serifatu Adetoyinbo, Owo Otun, Aralamo Saheed, Mufu Bello, Akeem Dasola, Akintoye Funmbi Olaitan

29/07/2024

LET TALK ABOUT IT

Awon obinrin kan wa, Bi won ba kuro nile oko kan, Tan lofe oko miran, Lati ile oko miran tan fe yen, Won atun mayan oko tan ko sile lale.

Kini eyin rope oma nfa iru nkan bai?
Se ale sope won si nife oko tan ko sile ju eyi tan sese felo ni?
Abi owo lo feju mo won lodo oko tan ko sile, tan tun fi pada n ni ibalopo pada pelu re?
Abi kani oko{pen*s} Oko tan ko sile dun ju ti oko tan sese fe lo?

Kini ero tiyin lori oro yi, Kini nkan teyin rope oma n fa?

Let Talk About It...

Good morning ma sir
29/07/2024

Good morning ma sir

Obinrin so ìwà nuÓ ní òun ó lórí ọkọBí ilé ọkọ o bá san eYẹ oro ẹnu rẹ wò,Elenu mímú kii gbé ilé okoWo ìbínú rẹ, onínú f...
12/04/2024

Obinrin so ìwà nu

Ó ní òun ó lórí ọkọ

Bí ilé ọkọ o bá san e

Yẹ oro ẹnu rẹ wò,
Elenu mímú kii gbé ilé oko

Wo ìbínú rẹ,
onínú fùfú kii gbádùn oko

Bawo ni ìwà owó re
Alágàbàgebè kii jèrè ọkọ re

Tun iwa re se iyawo.
Iwa ni Ewa Omobinrin Nile Oko.
Iyawo rere lodede oko Ade Ori Oko ni.
Esu koni pana ife loko-laya lase Edumare.

Akíyèsi pàtàkì             ÀJỌ.ṣe iwọ na ń da tiẹ?Níwòn ìgbà tí o bá sì wá lórí ilẹ̀ alààyè, dan-dan ni ko dajọ.Iwọ ọmọ ...
04/03/2024

Akíyèsi pàtàkì ÀJỌ.
ṣe iwọ na ń da tiẹ?
Níwòn ìgbà tí o bá sì wá lórí ilẹ̀ alààyè, dan-dan ni ko dajọ.
Iwọ ọmọ ènìyàn l'ọkunrin ati l'obinrin. Iwọ ni ọrọ yi ń ba a wí. O ni lọnà wo?

Wòó, so ri, labẹ bi o tí wù kó rí, niwọn ìgbà tí o bá sì ń bẹ láàyè, ni ti àjọ dídá, dan-dan ni.
Bó lówó, bi o sí tún lówó, bi lọla bi o sì tún lọla.
Bo lagbara, bi o sí tun lágbára, kódà bo jẹ Abirun. Ni ti ọrọ àjọ dídá, dan-dan ni.
Kálukú labẹ ọrùn lo ń da àjọ.

Ki ẹ sì má wòó, àjọ ti ọmọ ènìyàn k'ọkan ń dá labẹ ọrùn. Ki se àjọ ti wọn ki í kó, àjọ àdákó ni. Bi o bá ti da tó, bẹ lo se ma ko to.
Bi ọrọ ba wa ri bi èyí, Sir/Ma. Ti wọn ba sọpé, àjọ kan ọ, ki o wa ko tìẹ.
Njẹ o to lati yọju?
Bi wọn ba sì ba ọ ko àjọ tiẹ wá sile, njẹ o le gbàá?
Bàbáa, Mámaa, ẹ gbọ, irú àjọ wo ni ẹyin na ń da?
Àjọ ti ẹ ń fi ìwà ati ìṣe yin dá. Àjọ ti ẹ ń fi owó yin dá. Àjọ ti ẹ ń fi ọlá ati olà yin dá. Àjọ ti ẹ ń fi agbara ati àṣẹ tí ẹ ni da. Àjọ ti ẹ ń fi ẹwà ti ẹ ni da.
Bóyá ni ti dáradára tabi ni ti búburú. Ni ọjọ ti wọn ba kéde rẹ lọrun wípé, àjọ kan ọ, dan-dan ni, o ni lati kọọ.
KINI YO ṢẸLẸ NI ỌJỌ NA?

Njẹ irú ọmọ rẹ o ti gbé bayi, nítorí awọn àjọ nlánlá tí o ti ba da sílẹ?
Ki irú ọmọ rẹ lẹyìn rẹ ma baa ma fi ọ ré, wo àjọ da, wo àjọ wọ, wo àjọ ṣe.
Maṣe gbàgbé ọrọ Ọlọrun, èyí to wípé.
AWỌN BÀBÁ LO JẸ ÈSÓ ÀJÀRÀ TI KO PỌN. ÈYIN KAN ÀWỌN ỌMỌ WỌN
Ire oOoo

Address

Araromi Estate Ifo Ibogun Akinsinde Ifo
Utako

Telephone

+2348068189064

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Obirin rere ninu ile oko posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Establishment

Send a message to Obirin rere ninu ile oko:

Share