02/02/2024
Lets talk little about the Uses of This leafs (Iyalode ff,ati pupa) lapalapa leaf..
Die ninu iwulo ewe Botuje pupa ati funfun
1.AWURE ITAJA (AWORO OWO)
omunu ewe Iyalode ff, ati pupa Ao gun papo mon 200 Tuntun, ao gun mose Dudu ibile ao ko sinu ike funfun, ao ma fiwe Laaro pelu Handkerchief white, Ao tun mafi won ile ibi itaja wa, 2, AWURE ASINA AJE
ewe iyalode ff ati pupa ao gun papo mon imi ojo pupa, ao gun mose dudu ao kosinu ike ff, Wiwe laaro
Walai owo oni da lowo wa...
3, TO STOP BLEEDING FOR WOMAN THAT HER PERIOD IS NOT STOP, (Dida Eje tonya lara obirin to nri Eje duro)
Ao wa igi lapalapa funfun yii ao ge kekeke sinu ragolis, Ao fii omi warm water re fun 16hours obirin na yio mamun,
Laarin ojo 3, yio duro
5 AGBO FUN THYPROID, INFECTION, MALARIA,
AO JA EWE LAPALAPA PUPA YII AO GBO PELU OMI OSAN WEWE (LIME WATER) DADA, AO WA YO
A O MA MUN NII SIBI MEJIMEJI LARO LALE, LAARIN 3DAYS
A O YIN OLODUMARE
6, AGBO MALARIA (cold and headache relief)
Ao ja ewe Lapalapa Funfun mon igi, Ao see Lori ina fun wakati kan pere, ti o ba tutu tan ao ma mun
Ni stainless cup kokan 3 times lojumon
Lojo keji ara ti baale logo olorun....
7,.. OSE ATUDE ASINA
Ewe lapalapa funfun ati pupa, eepo obo die,, ewe ewuro die, ao gun mon ose lux white, ao ma we nii ojo Monday and Thursday,
Inu ike white lao kosi..
8.. AGBO TO REMOVE PROMISE AND FAILURE PELU OGUN IDILE
ao ja ewe lapalapa funfun ati pupa, pelu Ewe akoko, Ao se lori ina, ao fii eepo obo die tele agbo yii, ti o ba to bii 35minutes ao yo omi na ao fiwe ose atude tii aba nii,
Otun sise fun AJEGUN
HE GOODS FOR YAHOO BOYS...
E.T.C