ILU AWA OMO Yoruba

ILU AWA OMO Yoruba Lagos

Àmín Àṣẹ
20/04/2021

Àmín Àṣẹ

Ẹ kú ojúmọ́ gbogbo Ẹyin Ọmọ Karọ Ojire Bí
17/04/2021

Ẹ kú ojúmọ́ gbogbo Ẹyin Ọmọ Karọ Ojire Bí

Ọmọ Aráyé Ó Ni Tún Ọmọ Ìwọ Àti Èmi Daaaaaaaaaaaaaaaaaa. Àmín 🙏
07/04/2021

Ọmọ Aráyé Ó Ni Tún Ọmọ Ìwọ Àti Èmi Daaaaaaaaaaaaaaaaaa. Àmín 🙏

18/09/2020

Ewì, Oríkì Ìdílé tàbí tí ìlú. Orin ọjọ́ ìbí tàbí tí Ìbílẹ̀. Call for your engagement

Àmín Jésù
31/08/2020

Àmín Jésù

Ìtàn Ìgbése Ayé Abẹ́bi Àti Akanni Ẹ kú Ojú 👀 lọ́nà fún Ìtàn Ìgbése Ayé Abẹ́bi Àti Akanni
31/08/2020

Ìtàn Ìgbése Ayé Abẹ́bi Àti Akanni
Ẹ kú Ojú 👀 lọ́nà fún Ìtàn Ìgbése Ayé Abẹ́bi Àti Akanni

Ọna Kí Di M'ọjọ́ k'ọjọ́ máa là. Lónìí ọna èmi àti ẹyin kọ́ni dii.            Àmín
21/08/2020

Ọna Kí Di M'ọjọ́ k'ọjọ́ máa là. Lónìí ọna èmi àti ẹyin kọ́ni dii.
Àmín

Ẹ kú Dédé Àsìkò Yìí ooooooooÌròyìn ìlú Àwa Ọmọ Yorùbá lo gori afẹ́fẹ́.Ìròyìn tí fi tó wà létí wípé ìjọba àpapọ̀ yio se ì...
19/08/2020

Ẹ kú Dédé Àsìkò Yìí oooooooo
Ìròyìn ìlú Àwa Ọmọ Yorùbá lo gori afẹ́fẹ́.
Ìròyìn tí fi tó wà létí wípé ìjọba àpapọ̀ yio se ìpàdé pẹ̀lú àwọn ilé ìṣe tí wọn tí wa ni títí pá. Nígbà tí wọ́n José ìpàdé papọ bí ilé ìṣe òun yóò ṣe di ṣíṣí.
Àwọn ilé ìṣe tí ọ̀rọ̀ òun kàn ní
1. Ilé ìtura
2. Ilé ooti
3. Ilé ìgbà fẹ́ àti bẹ bẹ lọ.
Ijọba àpapọ̀ wá rọ àwọn tí yio wá síbi ìpàdé òun kì wá pẹ̀lú nkan ibomu (nose 👃 cover) kí wọn sì jìnà pípé jọ pẹ̀lú ọ̀gọ̀rọ̀ ẹ̀rọ. Ìjọba àpapọ̀ palase kí ilé ìṣe kọkan rán aṣojú márùn-ún tí yio dúró fún àwọn ilé ṣe kówa wọn.

Address

Puposola Area Abule Egba
Lagos

Telephone

+2348107851769

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ILU AWA OMO Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category