Ikoko Asa Tv

Ikoko Asa Tv 🔥 Premium Yoruba Content Creator 🔥
☑ Promoting Yoruba Culture
☑ Research and Philosophy

26/07/2024
27/06/2024

Bi Ina ba tan......

16/06/2024

Àkànlò èdè Yorùbá

04/06/2024

Oyún tí bomubómú bá ní ...

03/06/2024

Ìrìnàjò ọ̀sẹ̀ yìí máa pé wa láṣẹ Èdùmàrè

03/06/2024

Akúwárápá tó lu mágùn ...

12/06/2023

Nínú ìrìnàjò rẹ lọ́sẹ̀ tuntun yìí, ojú kò ní í tì ọ́ láṣẹ Èdùmàrè

19/01/2023

A fantastic group with recent update

Watch, Like, comment and don't forget to SUBSCRIBE 🥰
13/01/2023

Watch, Like, comment and don't forget to SUBSCRIBE 🥰

Ọmọ Yorùbá àtàtà. Ẹ jẹ́ ká jọ parí òwe yìí.Ọ̀jìnmì àgbẹ̀ kì í jà sí ìkókóró...
09/01/2023

Ọmọ Yorùbá àtàtà. Ẹ jẹ́ ká jọ parí òwe yìí.

Ọ̀jìnmì àgbẹ̀ kì í jà sí ìkókóró...



31/12/2022

31/12/2022

ÌWỌ KỌ́ LO NI Ẹ̀MÍ RẸ

Kàyééfì kan ló ṣẹlè.
Olùṣọ àgùntàn kan ló n bá bàbá kan jà nínú ìjọ rẹ̀. O sì n jẹ́ kó yé bàbá yìí wípé, tí ó bá kú, òun kò níí jẹ́kí wọ́n gbé òkú rẹ̀ wá sílé ìjọsìn òun láti ṣe adúrà ìkẹyìn fún-un.
Ṣùgbọ́n sí ìyàlẹ́nu gbogbo ènìyàn, bàbá yìí wa l’ára àwọn tó gbé pásítọ̀ yí lọ itẹ́ òkú lẹ́hìn ọ̀sẹ̀ kan ti Olùṣọ àgùntàn sọrọ náà, láti lọ sìn òkú rẹ̀. Ṣùgbón
Bàbá náà sì wà láyé d'ọjọ́ òní.

Afaa kan ló tún bínú sí ẹnikan, ó ní tó bá kú, òún kò ní kírun síi lára, ṣùgbón ọjọ́ kẹta, ẹni tí Àfáà n bínú sí yìí tún wà lára àwọn tó b'áwọn ṣe jìnísà àfáa yìí.
Olóògùn tó ní ẹni kàn kò níí di ọjọ́ méje, ṣe òun fúnra rẹ tíì d’ọjọ́ kẹta.
Ọlórun ní òun fẹ́ mú ọ, o wá n bójú w’ẹ̀hìn, ṣe o máa gburó ẹsẹ̀ rẹ̀ ni. Iwọ kọ lo ni ẹ̀mí rẹ
Ọlọrun le béèrè nǹkan rẹ̀, nígbà tó bá fẹ́. Dókítà tó níi, aláìsàn kò ní lò ju oṣù kàn lọ láyé, tó jẹ wipé dokita fúnra rẹ̀ kú, tí aláìsàn yè nkọ́.
Adájọ́ tó dájọ́ ikú fún ọ̀daràn,tí òun fúnra ṣe aláìsí nkọ́, tí ọdaràn sì tún n bẹ l'ayé.
Ẹni tó ra màlúù tó fẹ́ fí ṣe ayẹyẹ ọjọ ìbí, tó jẹ pé ẹ̀ran náà ni wọ́n pa ṣe òkú rẹ̀ nkọ́.
Ìwọ kọ́ lo ní ẹ̀mí rẹ, Yèé lérí asán. Ikú kó d'ọ́jọ́ àrùn kò dosu, ẹ jékí a gb'áyé ṣiṣẹ́ ire.

Bí ọdún ṣe n parí lónìí, Olorun kò níí fí ikú òjijì pa ọ́.
Okùn ẹ̀mí rẹ kò níí já. Agogo ọ̀fọ̀ kò níí lù nílé rẹ lâsẹ Èdùmàrè.
Wòlíì Fágbọrọ̀ ló n kí wa kú ìpalẹ̀mọ́ ọdún tuntun.
Èdè Yorùbá kò gbọdọ̀ parun.
0803368462.

Address

Contact 08038285032
Lagos

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ikoko Asa Tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Establishment

Send a message to Ikoko Asa Tv:

Share

Category