RomoKay Tv

RomoKay Tv please like the RomoKay tv page and follow it & Subscribe to Romokay Tv Channel on YouTube
thanks

16/05/2026

EWE EMILE WA FUN IWOSAN EDO INU ARA
Eyin temi e ku dede iwo yi, ajinde ara yio ma je o.
Gbogbo wa lati ri aworan ti o wa loke ise wo ni EWE EMILE yi nse, e fi ara bale lati gbo mi.
Eyin temi iwo ti o ba ni aisan jedojedo, tabi aisan inu ifun ni ewe yi wulo fun lopolopo, bawo ni a se fe lo ewe yi.
a o ja ewe Emile bi, leyin na a o san ninu omi dada, a o wa bu omi ti o mo si, a o wa se lori ina iseju marundinlogun, ilaji cup kan ni aaro, osan ati ale lojojumo
eyin temi oogun yi daju sugbon Olorun daju ju lo, mo gbadura fun yin lagbara eledumare a o ni rogun aisan tomotomo o amin.

16/05/2026

Address

Adebayo Abon Street Ilesa
Ilesa

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when RomoKay Tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Establishment

Send a message to RomoKay Tv:

Share

Category