Àṣàbí Òréke

Àṣàbí Òréke Promoting Yoruba language and culture.

Yah Allah guide those that has gone astray , forgive us all our sins ,and accept all our duas🤲 Jumuatu Mufeedah y"all,  ...
02/09/2022

Yah Allah guide those that has gone astray , forgive us all our sins ,and accept all our duas🤲 Jumuatu Mufeedah y"all, may we witness more of it on earth 🌎

01/07/2022

Is not me u people will oppress😋

The girl of Alhamdulilah🤗 Friday evening  .
01/07/2022

The girl of Alhamdulilah🤗 Friday evening .

03/06/2022
 .......AFẸ́FẸ́ ÌFẸ́.........Bí a bá r'ẹ́ni tí kìí fẹ́ gbọ́rọ̀ ìfẹ́ sétíTí i má n fajúro sọ́rọ̀ ìfẹ́Tí ó jẹ́ bórí àwọn ...
13/02/2022

.......AFẸ́FẸ́ ÌFẸ́.........

Bí a bá r'ẹ́ni tí kìí fẹ́ gbọ́rọ̀ ìfẹ́ sétí
Tí i má n fajúro sọ́rọ̀ ìfẹ́
Tí ó jẹ́ bórí àwọn tí wọn nífẹ́ ara wọn dénu
Inú burúkú a má a bìi , a dàbí kí nnkan ó tú wọn ká ni
Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ ti fẹ́ gbígbóná lù ú ni rí
Ṣùgbọ́n b'Ẹ́ṣin bá dáni àá tun n gùn ni
Ìfẹ́ kìí ṣe ohun tí ẹnikẹ́ni le è kẹ̀yìn sí tàbí bá bínú
Nítorí ifẹ́ borí ohun gbogbo láyé
Bí ìfẹ́ sọnù láyé ẹni rúdùrúdu layé ẹni n rí
Tútù ni afẹ́fẹ́ ìfẹ́ n fẹ́
Bí afẹ́fẹ́ ìfẹ́ bá fẹ́ síní lára gbogbo ìkórira ni á júbà ehoro
Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ a de ní mọ́lẹ̀ lá ì lo okùn
Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ amúnirẹ́rìín músẹ́ láì nìdìí
Kòsí ẹni tí afẹ́fẹ́ ìfẹ́ ò le è fẹ́ lù
Bó bá fẹ́ lu àgbàlagba a sọ́ di ọmọdé
Bó bá fẹ́ lu ọlọ́kàn líle a sọ ọ́ di ẹ̀dá tuntun
Mo règbèrí òkun
Mo rí bí wọ́n ti n dá bi ẹdun
Mo b'ùrìn b'ùrìn règbèrí ọ̀sà
Mo rí bí wọ́n ti n rọ̀ bí òwè
Mo dé ìlú ìfẹ́tẹ̀dó
Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ fẹ́ lú mí ara à mi yágágá
Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ fẹ́ lù mí ọkàn mi tutù bí i omi a fi òwúrọ̀ pọn
Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ fẹ́ ayọ̀, ire, ìtura sí mí lára
Inú ù mi n dùn ṣìnṣìn bí ẹni n lá ṣúgà
Afẹ́fẹ́ ìfẹ́ fẹ́ lù mí, mo mú ijó láì r'ílù.
ÈDÙMÀRÈ ò ní fẹ́ afẹ́fẹ́ ìfẹ́ gbóná lù wá o.

Àṣàbí òréke

EWÌ ÌFẸ́ CHALLENGE.....ÈDÌDÌ ÌFẸ́......Mo sáré ní pápá telenkú-telenkúMo rìn lààlà ọ̀nà yẹlẹnkù-yẹlẹnkùMo ti dé Àríwá,Gú...
06/02/2022

EWÌ ÌFẸ́ CHALLENGE
.....ÈDÌDÌ ÌFẸ́......

Mo sáré ní pápá telenkú-telenkú
Mo rìn lààlà ọ̀nà yẹlẹnkù-yẹlẹnkù
Mo ti dé Àríwá,Gúsù, iwọ̀ oorùn àti ilà oorùn láti wá ìfẹ́ kí Òòṣà òkè tó gbé mi pàdé ẹni bí ọkàn mi
Èdìdì ló dè wá pọ̀ onítémi , ẹni ọkàn mí yàn tí iná ìfẹ́ ẹ wa fi n jó lalala
Àmùrè ìfẹ́ ló dè wá pọ̀ tí a fi di kòríkòsùn
Àwámárídìí ni ifẹ́ bi orúkọ Elédùmarè Adániwáyé , nítorí òòṣà gan làwòkọ́ṣe ìfẹ́
Adániwáyé lọ́ sọ ìfẹ́ di Èdìdì
tí o fi di olólùfẹ́ méjì papọ̀
Òòṣà òkè ló so wá pọ̀ látọ̀run ìfẹ́ mi
Ìgbà èmi ìrẹ pàdé ni mo tó gbà pé ọ̀rọ̀ ìfẹ́ le sọ èèyàn di agánigàn lóòótọ́
nítorí bí mo bá dijú ìwọ ni mò n ri olólùfẹ́
Bí mo bá sùn ìwọ yìí kan ni mò n rí lójú àlá
Èdìdì ìfẹ́ ẹ wa ò gbọdọ̀ já láéláé
Ìfẹ́ Ẹyelé ni mo ní sí ẹ Onítèmi
N ò ní bá ọ jẹ, bá ọ mu, kó wá d'ọjọ́ ìṣòro kí n wá yẹ ri .
Mi ò ní fi igbá kan b'ọkan nínú fún ọ ìfẹ́ mi Ọjà ò níí kún ká a má mọ Àfín,
Igbó ò ní dí kí a má mọ̀rókò
Ọkùnrin ò ní pọ̀ kí n má mọ̀ ọ́ ìfẹ́ ọkàn mí
Èdìdì ìfẹ́ ti dè wá pọ̀ ná títí láéláé ni ìfẹ́ èmi ìrẹ Olólúfẹ́.

Àṣàbí òréke.

05/02/2022

People will always have something to say, just make sure you are doing the right thing. ÀṢÀBÍ ÒRÉKE.

05/02/2022

People will always have something to say , just make sure you do the right thing. Àṣàbí òréke.

May Almighty bless us beyond our expectation this new month 🤲
01/02/2022

May Almighty bless us beyond our expectation this new month 🤲

29/01/2022

We should all know that a culture is lost for every language we lose nd that language is the only means by which we can preserve our culture. Whatever disregard we have for our native language is obviously a ridiculous disrespect for our ancestry.

Like, comment, share 🙏

Akú ìsinmi òpin ọ̀sẹ̀ o

Address

Zone 3, No:47, Ijuri Lgbesa
Agbara

Telephone

+2348067438655

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Àṣàbí Òréke posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Establishment

Send a message to Àṣàbí Òréke:

Share